Gbogbo omo Ibadan Giramo

Gbogbo omo Ibadan Giramo; e yo e yo ninu Oluwa (2ce)
E ba Baba wa yo, Akinyele Baba wa (2ce)
Baba wa ti ja; O ti k’ogo ja; Ope ni f’ Oluwa (2ce)
Akoko oluko kekere, kekere o
Ke ke ke, Oluko agba, agbalagba
Ke ke ke Ojise Oluwa, Oluwa o
Ati ni opin akaso yi o, Bisobu;
Ise ti Baba wa Akinyele se, ko se e f’enu so (2ce)
A o so so so f’omo ta a bi o
A o ro ro ro f’oyun inu
At’awon kee kee kee o
Ti won nr’ojo l’orun
Akinyele bere , o k’omo yoyo; o ko ko
Alayande bere, o k’omo yo yo; o ko ko
Bere ko bere ko; o ko ko